OTAN ILE ANTHEM
Click Here to download Otan Ile Anthem
1. Niti Alafia Ise ati Iwa bi Olorun
Kos’ilu tale fiwe Ilu Otan Ile (2x)
Otan Afole awotep’ekun
Eje ka powopo gbeega
Tori kosibomiran ti a le lo
Ajo kole da bi ile.
2. Niti Alafia Ise ati Iwa bi Olorun
Kos’ilu tale fiwe Ilu Otan Ile (2x)
Otan ti gbogbo wa ni
Eje kagbe laruge
Koma gbodo baje lod’agba at’omode (2x)
3. Niti Alafia Ise ati Iwa bi Olorun
Kosi’lu tale fiwe Ilu Otan Ile (2x)
Baba Otan a gbewa
Koma nire gbogbo wa
Tesiwaju gbogbo Omo Otan Ile
4. Otan Afole awotep’ekun
Ejeka powopo gbeega online
Tori Kosibomiran ti a le lo
Ajo kole da bi ile.